Gomina ana nipinlẹ Ondo, Arakunrin Oluwarotimim Akeredolu ti bẹrẹ irin ajo tuntun lọ sinu aye miran. Ara, ọrẹ, ojulumọ ati awọn alabaṣepọ lo korajọ lati ṣẹyẹ ikẹyin fun un loni, ọjọ Ẹti, ọjọ ...
Rogbodiyan nla sẹlẹ n'ilu Akungba Akoko nipinlẹ Ondo bi ẹgbẹ awọn akẹkọọ fasiti Adekunle Ajasin to wa ni Akungba Akoko ṣe yabo gbogbo opopona ilu naa lati bere fun idajọ ododo lori iku Akẹkọọ fasiti ...